Events


OMOLUABI ID CARD! OMOLUABI ID CARD!!


Pelu ase ati atileyin Olori Alade gbogbo ni Ile Kaaro Oojire, Arole Oduduwa Olofin Adimula, Ooni Adeyeye Enitan Babatunde Ogunwusi, Ojaja II, The Ooni of Ife.

A'nfaani ti s'ile l'ati darapo mo egbe Igbimo Apapo Omoluabi-Yoruba Lagbaye: agbarijopo egbe fun gbogbo Omoluabi Oduduwa ni'ile t'oko, eyin odo l'okunrin ati L'obirin, Omode ati Agba'agba, L'oba l'oba, Ijoye, iyaloja, Babaloja, Onisowo ati gbogbo eyin otoku'lu ilu ile Kaaro Oojire.

Lati fi oruko sile ati gba card idanimo egbe OMOLUABI GOLD ID CARD ni N3,000 pere, ekan si ero ayelujara www.yorubacouncil.org, e'te atej'ise si omoluabiidcard@gmail.com,tabi k'epe TOBI si ori ero ibanis'oro: 08033931229 or 07084571953.

Gba Kaadi idanimo tire loni... ko so je aafani opojan'tirere!

Omoluabi Ni Mi, Omo K'aro Ojire ooo.


OMOLUABI ID CARD! OMOLUABI ID CARD!!

By the Royal authority and endorsement of the Arole Oduduwa Olofin Adimula, Ooni Adeyeye Enitan Babatunde Ogunwusi, Ojaja 11, The Ooni of Ife.

This is to invite all proud Sons and Daughters of Oduduwa globally to join the Igbimo Apapo Omoluabi-Yoruba Lagbaye: the apex umbrella body for all great Omoluabi Sons and Daughters of Oduduwa at home and in Diaspora.

We call on all Youths, Women, Teenagers and Children and Elders; including Royal Fathers, High Chiefs, Captains of industries and leaders of thoughts in Ile Kaaro Oojire Land to join us today.

For your membership registration and collection of your Omoluabi Gold ID Card at the cost of N3,000, please visit our portal: www.yorubacouncil.org.


Yoruba Council Logo Yoruba Council Logo Yoruba Council Logo Yoruba Council Logo Yoruba Council Logo Yoruba Council Logo Yoruba Council Logo

Phone

+234 80 3393 1229
+234 80 9393 1229
+234 80 6514 1956

Email

yorubacouncilworldwide@gmail.com
yorubacouncilofwomen@gmail.com
yorubacouncilofyouths@yahoo.com
ycywomoluabi@gmail.com